Lyrics: QDot – Question (Ibeere)

Views: 2699


 • 5
 •  
 •  
 •  
 •  

antras on the beat
qdot l’oruko mi o
alagbe
antras jo

ki lo pa iya ijebu
ibeere ehn…ibeere
won n bi mi lere
ibeere ehn…ibeere
shey eleyi ri owo s’aiye sha
ibeere ehn…ibeere
nibo lo ti ri owo na
ibeere ehn…ibeere
ibeere
o n bi mi o
ibeere ehn…ibeere
o ma n bi mi o
ibeere ehn…ibeere
oh la la la la e e ah ah
ibeere ehn…ibeere
oh la la la la e e ah ah
ibeere ehn…ibeere

mo ko gold s’orun
won ni panda ni
ba lo gucci versace
won a ni won ya ni
adete mi fe je iresi
oyinbo yin n su’kun n geesi
won fe mo idi abajo mi
baba loke, baba alajo mi
foolish people, foolish question
nibo lo ti ri owo, ta lo lo’wo
won lo se eniyan fun ogun owo
alapa ma sise pofolo
e ye bi mi lere mo o
foolish people
ki e ye bi mi leere mo o
iku to pa iya ijebi

ki lo pa iya ijebu
ibeere ehn…ibeere
won n bi mi lere
ibeere ehn…ibeere
shey eleyi ri owo s’aiye sha
ibeere ehn…ibeere
nibo lo ti ri owo na
ibeere ehn…ibeere
ibeere
o n bi mi o
ibeere ehn…ibeere
o ma n bi mi o
ibeere ehn…ibeere
oh la la la la e e ah ah
ibeere ehn…ibeere
oh la la la la e e ah ah
ibeere ehn…ibeere

[verse 2] oro mi lan n so ni gboro
gongo aso ni igboro
oro mi lan n so lo ni gboro
gongo aso ni igboro
baba bi ke kpo se
e je ko ye won pe enu o shey
regular n shey bi vip
bi olode n shey bi cip
e duro nibe
ki le di, ukwu ninu eod
agbo mi to tadi meyin agbara lo lo mu wa
bi agbo yin ba tadi meyin tipper lo ma pa
****
*****

ki lo pa iya ijebu
ibeere ehn…ibeere
won n bi mi lere
ibeere ehn…ibeere
shey eleyi ri owo s’aiye sha
ibeere ehn…ibeere
nibo lo ti ri owo na
ibeere ehn…ibeere
ibeere
o n bi mi o
ibeere ehn…ibeere
o ma n bi mi o
ibeere ehn…ibeere
oh la la la la e e ah ah
ibeere ehn…ibeere
oh la la la la e e ah ah
ibeere ehn…ibeere

****
*****
****
*****
****
*****
ogun orun ba won wi
ba won ja
antras on the beat

ki lo pa iya ijebu
ibeere ehn…ibeere
won n bi mi lere
ibeere ehn…ibeere
shey eleyi ri owo s’aiye sha
ibeere ehn…ibeere
nibo lo ti ri owo na
ibeere ehn…ibeere
ibeere
o n bi mi o
ibeere ehn…ibeere
o ma n bi mi o
ibeere ehn…ibeere
oh la la la la e e ah ah
ibeere ehn…ibeere
oh la la la la e e ah ah
ibeere ehn…ibeere


 • 5
 •  
 •  
 •  
 •  
Tags:
· · · ·

Comments

 • QDOT IS LIKE A BROTHER TO ME AND HOW REALY APPRECIATE IT IF HE SIGN ME TO TEACH HIM HOW TO DO VIDEO.

  AJAYI KAYODE July 18, 2015 7:04 am

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Free Naija Lyrics | Nigerian (Naija) Music Lyrics - MP3 Downloads